News flash

WEBINARS

Women Leaders
Saturday, April 19
Tokumbo Bodunde


NOW AVAILABLE!

Draft Program for the
Transformation of Society
Introduction Page
for sale Print   PDF

Present Time
January 2025
for sale Print   Digital

Tim Jackins
Keeping Our Own Minds
RCTU #81

ÌTSÍWÁJÚ ÀWN ÌLÀNÀ TÍ À NÍLÒ NÍ ÈDÈ YORÙBÁ

Ní àpéjọ àgbáyé wa, tí a máa ń ṣe ní dún mṛin méṛin, a máa ń ṣe ìlsíwájú àwn ìtṣ óṇ à wa, a sì máa ń fi ìmò e ḳ an lórí àwn ohun tí a f́ e, àti ohun tí ó e pàtàkì sì agbègbè wa àti àgbáyé. Ní àpéjàgbáyé wa ní dún 2022, èmi yóò dábàá pé kí a gba, kí a sì mú ̀r̀ ìyípadà ojú-j́ ló kúnkúndùn.

Láàrín àwn àpéjàgbáyé wa, ó jé ̣ojúe mi, ǵǵ bíi ni ìt́kasí kárí ayé láti fí àwn ètò tí a nílò síwájú. Ní dún 2017, mó dábàá ètò ìmúlò kan lórí ìyípadà ojú-j́ láti e ìtṣ óṇ à wa títí di àpéjọ àgbáyé ti ó ń bọ̀, èyí tí ó yká e ní dún 2021. Fún ipò pàjáwìrì tí ojú-j́ wá ĺẃ ĺẃ àti ìdí pé kí a gbé ìgbésè láì fi àkókò sòfùn. Mo ń fi àwọn ìlànà ẁnyí síl̀ láti darí wa títí di àpéjàgbáyé ti dún 2022:

Agbègbè RC, tí ó mọ ẹ̀rí tí ó hàn gbangba àti eewu tí ìyípadà ojú-j́ tí ènìyàn e okùnfà r̀, yóò e ètò àti àtìlỵ ìn fún àwn magbègbè r̀ láti lè dojú kìpèníjà yí àti wíwá ̀nà láti da dúró àti yíyipadà.

A óò e àtìĺyìn fún gbogbo àwn mọ ẹgb́ agbègbè RC láti lè mú ohùn tí ó ń dí wọn ĺẃ kúrò láti má kópa nínú akitiyan láti e ìt́jú àgbáyé. Ní e èyí, a mgbogbo ipá tí ìnilára kó láti dá wàhálà ojú-j́ sílàti ìwúlò e ìlòdì sì ìnilára láti lè wá ̀nà àbáy.

A ó fí ààyè síl̀ fún àwn mọ ẹgb́ agbègbè RC láti péjkí wṇ sì jíròrò lórí ̀r̀ náà, sísàti ìdàgbàsókè àwn ìm̀ràn tuntun, àwn ìlànà bí lílo wèbínà àti ìronú-àti-t́tísí àti àwn ̀nà míràn tí ó le mú òye wá.

Láti e iṣẹ́ pàtàkì yí, yíò nílò kí olúkúlùkù wá kojú àwn gbígbà sílìpṇ jú tí ó ti mú wá ronú bí aláìlágbára àti bí ni tí ó dá wa. Láti mú àwn gbígbà sílè ìpṇ jú ẁnyí kúrò, a óò ḱ ̀ḱ láti máa t̀síwájú- àti fífi ẃ so ẃp̀ àti ìgbḳ èḷé tí ó p- nínú ìbásep̀ wá p̀lú àwn ènìyàn àti e alátakò sí àwn ìlànà tì kò bójú mu.

A lè e ìrànĺẃ fún ara wa láti ḱ ̀ḱ àti lóye nípa ipò tí a wà ĺẃĺẃ, p̀lú ìkópa ni-kọọkan, àwn ènìyàn àbínibí, àti àwn gb́ tí ń ṣié láti dá ìyípadà ojú-j́ dúró. Èyí óò fún wa ní ìm̀ tààrà àti tako àwn gbígbà sílìpṇ jú tí ìpínyà àti àìní olùrànĺẃ.
A óò tún pín ìm
̀ àti ìe wá, kí àwọn tí ń ṣié lórí ìyípadà ojú-j́ lè ié dáradára síi.

Orúkmi ni
Adékúnlé Akinolá Agbègbè RC, Ìlú Àkúré, Orílè-èdè Nàìjíríà.


Last modified: 2022-12-16 23:40:10+00