News flash

WEBINARS

Impact of U.S. Election
Results on Climate
Action in the U.S.

Saturday, January 4
Sunday, January 5
Diane Shisk

 

ÌTẸSÍWÁJÚ ÀWỌN ÌLÀNÀ TÍ À NÍLÒ NÍ ÈDÈ YORÙBÁ

Ní àpéjọ àgbáyé wa, tí a máa ń ṣe ní ọdún mẹ́rin mẹ́rin, a máa ń ṣe ìlọsíwájú àwọn ìtọ́sọ́nà wa, a sì máa ń fi ìmò ṣe ọ̀kan lórí àwọn ohun tí a fẹ́ ṣe, àti ohun tí ó ṣe pàtàkì sì agbègbè wa àti àgbáyé. Ní àpéjọ àgbáyé wa ní ọdún 2022, èmi yóò dábàá pé kí a gba, kí a sì mú ọ̀rọ̀ ìyípadà ojú-ọjọ́ ló kúnkúndùn.

Láàrín àwọn àpéjọ àgbáyé wa, ó jẹ́ ojúṣe mi, gẹ́gẹ́ bíi ẹni ìtọ́kasí kárí ayé láti fí àwọn ètò tí a nílò síwájú. Ní ọdún 2017, mó dábàá ètò ìmúlò kan lórí ìyípadà ojú-ọjọ́ láti ṣe ìtọ́sọ́nà wa títí di àpéjọ àgbáyé ti ó ń bọ̀, èyí tí ó yẹ ká ṣe ní ọdún 2021. Fún ipò pàjáwìrì tí ojú-ọjọ́ wálọẃọ́lọ́wọ́àtiìdípékíagbéìgbésèláìfiàkókòsòfùn.

Mońfiàwọnìlànàwọǹyísílẹ̀ láti darí wa títí di àpéjọ àgbáyé ti ọdún 2022:

Agbègbè RC, tí ó mọ ẹ̀rí tí ó hàn gbangba àti eewu tí ìyípadà ojú-ọjọ́ tí ènìyàn ṣe okùnfà rẹ̀, yóò ṣe ètò àti àtìlẹ́yìn fún àwọn ọmọ agbègbè rẹ̀ láti lè dojú kọ ìpèníjà yí àti wíwá ọ̀nà láti da dúró àti yíyipadà.

A óò ṣe àtìlẹý ìn fún gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbègbè RC láti lè mú ohùn tí ó ń dí wọn lọ́wọ́ kúrò láti má kópa nínú akitiyan láti ṣe ìtọ́jú àgbáyé. Ní ṣíṣe èyí, a mọ gbogbo ipá tí ìnilára kó láti dá wàhálà ojú-ọjọ́ sílẹ àti ìwúlò ṣíṣe ìlòdì sì ìnilára láti lè wá ọǹ à àbáyọ.

A ó fí ààyè sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbègbè RC láti péjọ kí wọ́n sì jíròrò lórí ọr̀ ọ̀ náà, sísọ àti ìdàgbàsókè àwọn ìmọ̀ràn tuntun, àwọn ìlànà bí lílo wèbínà àti ìronú-àti-tẹ́tísí àti àwọn ọ̀nà míràn tí ó le mú òye wá.

Látiṣeiṣẹ́pàtàkìyí,yíònílòkíolúkúlùkùwákojúàwọngbígbàsílẹìpóṇjútíótimú wá ronú bí aláìlágbára àti bí ẹni tí ó dá wa. Láti mú àwọn gbígbà sílè ìpọ́njú wọ̀nyí kúrò, a óò kọ́ ẹ̀kọ́ láti máa tẹs̀ íwájú- àti fífi ọwọ́ so wọ́pọ̀ àti ìgbẹ́kẹ̀lé tí ó pọ - nínú ìbásepọ̀ wá pẹ̀lú àwọn ènìyàn àti ṣíṣe alátakò sí àwọn ìlànà tì kò bójú mu.

A lè ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ara wa láti kọ́ ẹ̀kọ́ àti lóye nípa ipò tí a wà lọẃ ọ́lọ́wọ́, pẹ̀lú ìkópa ẹni-kọọkan, àwọn ènìyàn àbínibí, àti àwọn ẹgbẹ́ tí ń ṣiṣé láti dá ìyípadà ojú-ọjọ́ dúró. Èyí óò fún wa ní ìmọ̀ tààrà àti tako àwọn gbígbà sílẹ ìpọ́njú tí ìpínyà àti àìní olùrànlọ́wọ́.

A óò tún pín ìmọ̀ àti ìṣe wá, kí àwọn tí ń ṣiṣé lórí ìyípadà ojú-ọjọ́ lè ṣiṣé dárad

Orúkọ mi ni
Adékúnlé Akinolá Agbègbè RC, Ìlú Àkúré, Orílè-èdè Nàìjíríà.


Last modified: 2022-12-16 23:25:35+00